Gẹn 24:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi obinrin na kò ba si fẹ́ tẹle ọ, njẹ nigbana li ọrùn rẹ yio mọ́ kuro ni ibura mi yi: ọkan ni, ki iwọ máṣe tun mu ọmọ mi pada lọ sibẹ̀.

Gẹn 24

Gẹn 24:1-15