Gẹn 24:67 Yorùbá Bibeli (YCE)

Isaaki si mu u wá si inu agọ́ Sara, iya rẹ̀, o si mu Rebeka, o di aya rẹ̀; o si fẹ́ ẹ; a si tu Isaaki ninu lẹhin ikú iya rẹ̀.

Gẹn 24

Gẹn 24:60-67