Gẹn 24:61 Yorùbá Bibeli (YCE)

Rebeka si dide, ati awọn omidan rẹ̀, nwọn si gùn awọn ibakasiẹ, nwọn si tẹle ọkunrin na: iranṣẹ na si mu Rebeka, o si ba tirẹ̀ lọ.

Gẹn 24

Gẹn 24:56-67