Gẹn 24:53 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iranṣẹ na si yọ ohun èlo fadaka, ati èlo wurà jade, ati aṣọ, o si fi wọn fun Rebeka: o si fi ohun iyebiye pẹlu fun arakunrin rẹ̀ ati fun iya rẹ̀.

Gẹn 24

Gẹn 24:52-57