Gẹn 24:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sara, aya oluwa mi, si bí ọmọ kan fun oluwa mi nigbati on (Sara) gbó tán: on li o si fi ohun gbogbo ti o ni fun.

Gẹn 24

Gẹn 24:33-44