Gẹn 24:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abrahamu si wi fun iranṣẹ rẹ̀, agba ile rẹ̀ ti o ṣe olori ohun gbogbo ti o ni pe, Emi bẹ̀ ọ, fi ọwọ rẹ si abẹ itan mi;

Gẹn 24

Gẹn 24:1-7