Gẹn 23:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃kọ, Oluwa mi, gbọ́ ti emi, mo fi oko na fun ọ, ati ihò ti o wà nibẹ̀, mo fi fun ọ: li oju awọn ọmọ awọn enia mi ni mo fi i fun ọ: sin okú rẹ.

Gẹn 23

Gẹn 23:1-14