Gẹn 23:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) SARA si di ẹni ẹtadilãdoje ọdún: iye ọdún aiye Sara li eyi. Sara si kú ni Kirjat-arba; eyi na ni Hebroni ni