Gẹn 22:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abrahamu si mu igi ẹbọ sisun na, o si dì i rù Isaaki, ọmọ rẹ̀; o si mu iná li ọwọ́ rẹ̀, ati ọbẹ; awọn mejeji si jùmọ nlọ.

Gẹn 22

Gẹn 22:5-12