Gẹn 22:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, lẹhin nkan wọnyi, li a sọ fun Abrahamu pe, kiyesi i, Milka, on pẹlu si ti bimọ fun Nahori, arakunrin rẹ;

Gẹn 22

Gẹn 22:13-24