Gẹn 22:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wipe, Emi tikalami ni mo fi bura, li OLUWA wi, nitori bi iwọ ti ṣe nkan yi, ti iwọ kò si dù mi li ọmọ rẹ, ọmọ rẹ na kanṣoṣo:

Gẹn 22

Gẹn 22:11-20