Gẹn 21:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọmọ na si dàgba, a si já a li ẹnu ọmú: Abrahamu si sè àse nla li ọjọ́ na ti a já Isaaki li ẹnu ọmú.

Gẹn 21

Gẹn 21:4-12