Gẹn 21:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe li akokò na, ni Abimeleki ati Fikoli, olori ogun rẹ̀, wi fun Abrahamu pe, Ọlọrun pẹlu rẹ ni gbogbo ohun ti iwọ nṣe.

Gẹn 21

Gẹn 21:21-29