Gẹn 21:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si lọ, o joko kọju si i, li ọ̀na jijìn rére, o tó bi itafasi kan: nitori ti o wipe, Ki emi má ri ikú ọmọ na. O si joko kọju si i, o gbé ohùn rẹ̀ soke, o nsọkun.

Gẹn 21

Gẹn 21:12-17