Gẹn 21:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abrahamu si dide ni kutukutu owurọ̀, o mu àkara ati ìgo omi kan, o fi fun Hagari, o gbé e lé e li ejika, ati ọmọ na, o si lé e jade: on si lọ, o nrìn kakiri ni ijù Beer-ṣeba.

Gẹn 21

Gẹn 21:8-21