Gẹn 21:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li o ṣe wi fun Abrahamu pe, Lé ẹrubirin yi jade ti on ti ọmọ rẹ̀: nitoriti ọmọ ẹrubirin yi ki yio ṣe arole pẹlu Isaaki, ọmọ mi.

Gẹn 21

Gẹn 21:5-20