Gẹn 20:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Abrahamu si wi niti Sara aya rẹ̀ pe, Arabinrin mi ni: Abimeleki ọba Gerari si ranṣẹ, o si mu Sara.

Gẹn 20

Gẹn 20:1-3