Gẹn 2:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati inu ilẹ li OLUWA Ọlọrun mu onirũru igi hù jade wá, ti o dara ni wiwò, ti o si dara fun onjẹ; ìgi ìye pẹlu lãrin ọgbà na, ati igi ìmọ rere ati buburu.

Gẹn 2

Gẹn 2:1-13