Gẹn 2:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA Ọlọrun si fi erupẹ ilẹ mọ enia; o si mí ẹmí ìye si ihò imu rẹ̀; enia si di alãye ọkàn.

Gẹn 2

Gẹn 2:1-15