Gẹn 2:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati olukuluku igi igbẹ ki o to wà ni ilẹ, ati olukuluku eweko igbẹ ki nwọn ki o to hù: OLUWA Ọlọrun kò sa ti rọ̀jo si ilẹ, kò si sí enia kan lati ro ilẹ.

Gẹn 2

Gẹn 2:1-6