Gẹn 2:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Adamu si sọ ẹran-ọ̀sin gbogbo, ati ẹiyẹ oju-ọrun, ati ẹranko igbẹ gbogbo, li orukọ; ṣugbọn fun Adamu a kò ri oluranlọwọ ti o dabi rẹ̀ fun u.

Gẹn 2

Gẹn 2:11-25