Gẹn 2:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ninu igi ìmọ rere ati bururu nì, iwọ kò gbọdọ jẹ ninu rẹ̀: nitoripe li ọjọ́ ti iwọ ba jẹ ninu rẹ̀ kikú ni iwọ o kú.

Gẹn 2

Gẹn 2:9-19