Gẹn 19:33 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si mu baba wọn mu ọti-waini li oru na: eyi akọbi wọle tọ̀ ọ, o si sùn tì baba rẹ̀; on kò si mọ̀ igbati o dubulẹ, ati igbati o dide.

Gẹn 19

Gẹn 19:28-38