Gẹn 19:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wò ìha Sodomu on Gomorra, ati ìha gbogbo ilẹ àgbegbe wọnni, o si wò o, si kiyesi i, ẽfin ilẹ na rú soke bi ẽfin ileru.

Gẹn 19

Gẹn 19:20-38