Gẹn 19:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li OLUWA rọ̀jo sulfuri (okuta ina) ati iná lati ọdọ OLUWA lati ọrun wá si ori Sodomu on Gomorra:

Gẹn 19

Gẹn 19:23-29