Gẹn 19:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yara, salà sibẹ̀; nitori emi kò le ṣe ohun kan titi iwọ o fi de ibẹ̀. Nitorina li a ṣe npè orukọ ilu na ni Soari.

Gẹn 19

Gẹn 19:14-24