Gẹn 18:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu orí-amọ́, ati wàra, ati ẹgbọrọ malu ti o sè, o si gbé e kalẹ niwaju wọn: on si duro tì wọn li abẹ igi na, nwọn si jẹ ẹ.

Gẹn 18

Gẹn 18:1-12