Gẹn 18:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bọya marun a dín ninu ãdọta olododo na: iwọ o ha run gbogbo ilu na nitori marun? On si wipe, Bi mo ba ri marunlelogoji nibẹ̀, emi ki yio run u.

Gẹn 18

Gẹn 18:26-33