Gẹn 18:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

O ha dára, ti iwọ o fi ṣe bi irú eyi, lati run olododo pẹlu enia buburu; ti awọn olododo yio fi dabi awọn enia buburu, o ha dára: Onidajọ gbogbo aiye ki yio ha ṣe eyi ti o tọ́?

Gẹn 18

Gẹn 18:23-30