Gẹn 18:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina Sara rẹrin ninu ara rẹ̀ wipe, Lẹhin igbati mo di ogbologbo tan, emi o ha li ayọ̀, ti oluwa mi si di ogbologbo pẹlu?

Gẹn 18

Gẹn 18:9-15