Gẹn 17:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si fi ilẹ ti iwọ ṣe alejo nibẹ̀ fun ọ, ati fun irú-ọmọ rẹ lẹhin rẹ, gbogbo ilẹ Kenaani ni iní titi lailai; emi o si ma ṣe Ọlọrun wọn.

Gẹn 17

Gẹn 17:1-11