Gẹn 17:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹniti a bí ni ile rẹ, ati ẹniti a fi owo rẹ rà, a kò le ṣe alaikọ ọ ni ilà: bẹ̃ni majẹmu mi yio si wà li ara nyin ni majẹmu aiyeraiye.

Gẹn 17

Gẹn 17:6-23