Gẹn 17:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi ni majẹmu mi, ti ẹnyin o ma pamọ́ lãrin temi ti nyin, ati lãrin irú-ọmọ rẹ, lẹhin rẹ; gbogbo ọmọkunrin inu nyin li a o kọ ni ilà.

Gẹn 17

Gẹn 17:8-16