Gẹn 17:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

NIGBATI Abramu si di ẹni ọkandilọgọrun ọdún, OLUWA farahàn Abramu, o si wi fun u pe, Emi li Ọlọrun Olodumare; mã rìn niwaju mi, ki iwọ ki o si pé.

Gẹn 17

Gẹn 17:1-7