Gẹn 16:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Angeli OLUWA na si wi fun u pe, kiyesi i iwọ loyun, iwọ o si bí ọmọkunrin, iwọ o si sọ orukọ rẹ̀ ni Iṣmaeli; nitoriti OLUWA ti gbọ́ ohùn arò rẹ.

Gẹn 16

Gẹn 16:1-16