Gẹn 15:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun u pe, Mu ẹgbọrọ malu ọlọdun mẹta fun mi wá, ati ewurẹ ọlọdun mẹta, ati àgbo ọlọdun mẹta, ati oriri kan, ati ọmọ ẹiyẹle kan.

Gẹn 15

Gẹn 15:1-13