Gẹn 15:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ni iran kẹrin, nwọn o si tun pada wá nihinyi: nitori ẹ̀ṣẹ awọn ara Amori kò ti ikún.

Gẹn 15

Gẹn 15:14-21