Gẹn 14:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọba Sodomu si jade, ati ọba Gomorra, ati ọba Adma, ati ọba Seboimu, ati ọba Bela, (eyini ni Soari;) nwọn si tẹgun si ara wọn li afonifoji Siddimu;

Gẹn 14

Gẹn 14:1-14