Gẹn 13:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si ṣe irú-ọmọ rẹ bi erupẹ ilẹ: tobẹ̃ bi o ba ṣepe enia kan ba le kà iye erupẹ ilẹ, on li a o to le kaye irú-ọmọ rẹ pẹlu.

Gẹn 13

Gẹn 13:14-18