Gẹn 12:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Farao si paṣẹ fun awọn ọkunrin rẹ̀ nitori Abramu: nwọn si sìn i jade lọ, ati aya rẹ̀, ati ohun gbogbo ti o ni.

Gẹn 12

Gẹn 12:11-20