Gẹn 11:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina li a ṣe npè orukọ ilu na ni Babeli; nitori ibẹ̀ li OLUWA gbe dà ède araiye rú, lati ibẹ̀ lọ OLUWA si tú wọn ká kiri si ori ilẹ gbogbo.

Gẹn 11

Gẹn 11:1-15