Gẹn 11:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ wá na, ẹ jẹ ki a sọkalẹ lọ, ki a dà wọn li ède rú nibẹ̀, ki nwọn ki o máṣe gbedè ara wọn mọ́.

Gẹn 11

Gẹn 11:1-12