Gẹn 11:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati Abramu ati Nahor si fẹ aya fun ara wọn: orukọ aya Abramu ni Sarai; ati orukọ aya Nahori ni Milka, ọmọbinrin Harani, baba Milka, ati baba Iska.

Gẹn 11

Gẹn 11:21-32