Gẹn 10:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati ọdọ awọn wọnyi li a ti pín erekuṣu awọn orilẹ-ède ni ilẹ wọn, olukuluku gẹgẹ bi ohùn rẹ̀; gẹgẹ bi idile wọn, li orilẹ-ède wọn.

Gẹn 10

Gẹn 10:1-15