Gẹn 10:31 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn wọnyi li ọmọ Ṣemu, gẹgẹ bi idile wọn, gẹgẹ bi ohùn wọn, ni ilẹ wọn, li orilẹ-ède wọn.

Gẹn 10

Gẹn 10:29-32