Gẹn 10:25-28 Yorùbá Bibeli (YCE)

25. Ati fun Eberi li a bí ọmọkunrin meji; orukọ ekini ni Pelegi; nitori nigba ọjọ́ rẹ̀ ni ilẹ yà; orukọ arakunrin rẹ̀ ni Joktani.

26. Joktani si bí Almodadi, ati Ṣelefi, ati Hasarmafeti, ati Jera,

27. Ati Hadoramu, ati Usali, ati Dikla,

28. Ati Obali, ati Abimaeli, ati Ṣeba,

Gẹn 10