Gẹn 10:21-23 Yorùbá Bibeli (YCE)

21. Fun Ṣemu pẹlu, baba gbogbo awọn ọmọ Eberi, ẹgbọn Jafeti ati fun on li a bimọ.

22. Awọn ọmọ Ṣemu: Elamu, ati Aṣṣuri, ati Arfaksadi, ati Ludi, ati Aramu.

23. Ati awọn ọmọ Aramu; Usi, ati Huli, ati Geteri, ati Maṣi.

Gẹn 10