Gẹn 10:13-15 Yorùbá Bibeli (YCE)

13. Misraimu si bí Ludimu, ati Anamimu, ati Lehabimu, ati Naftuhimu,

14. Ati Patrusimu, ati Kasluhimu (lati ọdọ ẹniti Filistimu ti wá), ati Kaftorimu.

15. Kenaani si bí Sidoni akọbi rẹ̀, ati Heti,

Gẹn 10