Gẹn 10:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) IRAN awọn ọmọ Noa ni wọnyi, Ṣemu, Hamu, ati Jafeti: ati fun wọn li a si bí ọmọ lẹhin kíkun-omi. Awọn