Gẹn 1:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si wipe, kiye si i, Mo fi eweko gbogbo ti o wà lori ilẹ gbogbo ti nso eso fun nyin, ati igi gbogbo ninu eyiti iṣe igi eleso ti nso; ẹnyin ni yio ma ṣe onjẹ fun.

Gẹn 1

Gẹn 1:27-31